Àkójopô Orin Aládùn pêlú Tonik Solfa

1,200.00

Ìwé yìí jë àkójqpô orin aládùn kékèké fún ìgbádùn àwqn ènìyàn, àti pàápàá fún àwqn qmq ilé-êkö níbi tí wön ti å sq èdè Yorùbá.
Ipa mërin ni àwqn orin wônyí pín sí. Ipa kìíní jë àkójqpô orin ìbílê; ipa kejì jë orin eré ìdárayá; ipa kvta jv mö orin eré orí ìtàgé; ipa kvrin sì jë orin ìbêrê, ìparí àti ìdágbére fún ilé-êkö.
Gbogbo ilé-êkö tí ó bá ní dùùrù tàbí fèrè ni yí ó le kq àwqn orin wônyí fún àâfààní àwqn qmq ilé-êkö wqn, pàápàá jùlq àwqn qmqdé.
Ó dámi lójú pé gbogbo àwqn ènìyàn tí ó bá ra ìwé orin yìí pêlú tqnik sqlfa rê ni yí ó gbádùn ìwé náà gan-an.

Description